Oníwàásù 7:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe sọ wí pé, “Kí ni ìdí tí àtijọ́ fi dára ju èyí?”Nítorí pé, kò mú ọgbọ́n wá láti bèèrè irú ìbéèrè bẹ́ẹ̀.

Oníwàásù 7

Oníwàásù 7:1-12