Oníwàásù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wà láìní ìtumọ̀, ó lọ nínú òkùnkùn, nínú òkùnkùn sì ni orúkọ rẹ̀ farapamọ́ sí.

Oníwàásù 6

Oníwàásù 6:1-12