Oníwàásù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aṣán ni ọ̀pọ̀ àlá àti ọ̀rọ̀ púpọ̀. Nítorí náà dúró nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run.

Oníwàásù 5

Oníwàásù 5:1-14