Oníwàásù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn kò le è ṣe ohun kóhun tí ó dára jù pé kí ó jẹ kí ó sì mu, kí ó sì rí ìtẹ́lọ́rùn nínú iṣẹ́ rẹ̀. Mo rí wí pé eléyìí pẹ̀lú wá láti ọwọ́ Ọlọ́run.

Oníwàásù 2

Oníwàásù 2:16-26