Oníwàásù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú ọlọ́gbọ́n ń bẹ lágbárí rẹ̀,nígbà tí aṣiwèrè ń rìn nínú òkùnkùn,ṣùgbọ́n mo wá padà mọ̀wí pé ìpín kan náà ni ó n dúró de ìsọ̀rí àwọn ènìyàn méjèèjì.

Oníwàásù 2

Oníwàásù 2:7-22