Oníwàásù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rò nínú ọkàn mi, “Wá níṣinṣin yìí, èmi yóò sì dán ọ wò pẹ̀lú ìgbádùn láti ṣe àwárí ohun tí ó dára.” Ṣùgbọ́n eléyìí náà já sí asán.

Oníwàásù 2

Oníwàásù 2:1-6