Oníwàásù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rántí rẹ̀—kí okùn fàdákà tó já,tàbí kí ọpọ́n wúrà tó fọ́;kí ìṣa tó fọ́ níbi ìṣun,tàbí kí àyíká-kẹ̀kẹ́ kí ó tó kán níbi kànga.

Oníwàásù 12

Oníwàásù 12:5-7