Oníwàásù 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ilẹ̀kùn sí ìgboro yóò tìtí ariwo ọlọ yóò dákẹ́;nígbà tí àwọn ènìyàn yóò dìde sí ariwo àwọn ẹyẹṣùgbọ́n gbogbo orin wọn yóò máa lọ ilẹ̀.

Oníwàásù 12

Oníwàásù 12:1-5