Oníwàásù 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níṣinsìn yìí,òpin gbogbo ọ̀rọ̀ tí a gbọ́ ni pé:Bẹ̀rù Ọlọ́run, kí o sì pa òfin rẹ̀ mọ́,nítorí èyí ni ojúṣe gbogbo ènìyàn.

Oníwàásù 12

Oníwàásù 12:6-14