Oníwàásù 12:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oníwàásù wádìí láti rí àwọn ọ̀rọ̀ tí ó tọ̀nà, ohun tí ó kọ sì dúró ṣinṣin ó sì jẹ́ òtítọ́.

Oníwàásù 12

Oníwàásù 12:5-14