Oníwàásù 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rántí Ẹlẹ́dàá rẹní ọjọ́ èwe rẹ,nígbà tí ọjọ́ ibi kò tíì déàti tí ọdún kò tíì ní ṣun mọ́ etílé, nígbà tí ìwọ yóò wí pé,“Èmi kò ní ìdùnnú nínú wọn”

Oníwàásù 12

Oníwàásù 12:1-4