Oníwàásù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n jẹ́ kí ènìyàn jẹ̀gbádùn gbogbo iye ọdúntí ó le è lò láyéṣùgbọ́n jẹ́ kí ó rántí ọjọ́ òkùnkùnnítorí wọn ó pọ̀Gbogbo ohun tí ó ń bọ̀ asán ni.

Oníwàásù 11

Oníwàásù 11:1-10