Oníwàásù 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun ibi kan wà tí mo ti rí lábẹ́ oòrùn,irú àṣìṣe tí ó dìde láti ọ̀dọ̀ alákòóso.

Oníwàásù 10

Oníwàásù 10:1-15