Oníwàásù 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn ọlọgbọ́n a máa sí sí ohun tí ó tọ̀nà,ṣùgbọ́n ọkàn òmùgọ̀ sí ohun tí kò dára.

Oníwàásù 10

Oníwàásù 10:1-10