Oníwàásù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ejò bá sán ni kí a tó lo oògùn rẹ̀,kò sí èrè kankan fún olóògùn rẹ̀.

Oníwàásù 10

Oníwàásù 10:8-17