Onídájọ́ 9:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Ọlọ́run san ẹ̀san ìwà búburú ti Ábímélékì hù sí baba rẹ̀ ní ti pípa tí ó pa, àwọn àádọ́rin (70) arákùnrin rẹ̀.

Onídájọ́ 9

Onídájọ́ 9:52-57