Onídájọ́ 9:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábímélékì tún lọ sí Tébésì, ó yí ìlú náà ká pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun, ó sì ṣẹ́gun rẹ̀.

Onídájọ́ 9

Onídájọ́ 9:47-56