Onídájọ́ 9:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábímélékì àti gbogbo àwọn ogun rẹ̀ sì jáde ní òru, wọ́n sì lúgọ (sápamọ́) sí ọ̀nà mẹ́rin yí Ṣékémù ká.

Onídájọ́ 9

Onídájọ́ 9:31-35