Onídájọ́ 8:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò sì rántí Olúwa Ọlọ́run wọn, ẹni tí ó gbà wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀ta wọn gbogbo tí ó wà ní gbogbo àyíká wọn.

Onídájọ́ 8

Onídájọ́ 8:27-35