Onídájọ́ 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú àwọn àgbààgbà ìlú náà, ó sì fi kọ́ àwọn Ṣúkótì lọ́gbọ́n nípa jíjẹ wọ́n níyà pẹ̀lú àwọn ẹ̀gún aṣálẹ̀ àti ẹ̀gún ọ̀gàn.

Onídájọ́ 8

Onídájọ́ 8:8-22