Onídájọ́ 7:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí fún Gídíónì pé, “Àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ọkùnrin tí ó lá omi ni èmi yóò lò láti gbà yín là àti láti fi ogun Mídíánì lé yín lọ́wọ́. Jẹ́ kí àwọn tókù padà sí ilé wọn.”

Onídájọ́ 7

Onídájọ́ 7:1-17