Onídájọ́ 6:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru náà Ọlọ́run ṣe bẹ́ẹ̀, awọ irun àgùntàn nìkan ni ó gbẹ; gbogbo ilẹ̀ yóòkù sì tutù nítorí ìrì.

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:39-40