Onídájọ́ 6:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì sì dáhùn pé, nísinsìn yìí tí mo bá bá ojúrere rẹ pàdé, fún mi ní àmì pé ìwọ ni ń bá mi sọ̀rọ̀.

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:14-25