Onídájọ́ 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì sì dáhùn pé, “Alàgbà Báwo ni èmi ó ṣe gba Ísírẹ́lì là? Ìdílé mi ni ó jẹ́ aláìlera jù ní Mànásè, àti pé èmi ni ó sì kéré jù ní ìdílé bàbá mi.”

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:13-20