Onídájọ́ 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ańgẹ́lì Olúwa fara han Gídíónì, ó wí fún un pé, “Olúwa wà pẹ̀lú rẹ, akọni ológun.”

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:8-22