Onídájọ́ 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dèbórà, wòlíì-obìnrin, aya Lápídótì ni olórí àti asíwájú àwọn ará Ísírẹ́lì ní àsìkò náà.

Onídájọ́ 4

Onídájọ́ 4:1-12