Onídájọ́ 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A fi àwọn ènìyàn náà sílẹ̀ láti dán àwọn Ísírẹ́lì wò bóyá wọn yóò gbọ́ran sí àwọn òfin Olúwa, èyí tí ó ti fi fún àwọn baba wọn láti ipaṣẹ̀ Móṣè.

Onídájọ́ 3

Onídájọ́ 3:1-10