Onídájọ́ 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éhúdù gbé owó orí náà lọ bí ó ti máa ń ṣe tẹ́lẹ̀ ó sì fi fún Égílónì ẹni tí ó sanra púpọ̀.

Onídájọ́ 3

Onídájọ́ 3:12-27