Onídájọ́ 19:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

òun sì wí fún obìnrin náà pé, “Dìde jẹ́ kí a máa bá ọ̀nà wa lọ.” Ṣùgbọ́n òun kò dá a lóhùn. Nígbà náà ni ọkùnrin náà gbé e lé orí i kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, ó sì kọjá lọ sí ilé e rẹ̀.

Onídájọ́ 19

Onídájọ́ 19:18-30