Onídájọ́ 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní alẹ́ ọjọ́ náà ọkùnrin arúgbó kan láti àwọn òkè Éfúráímù, ṣùgbọ́n tí ń gbé ní Gíbíà (ibẹ̀ ni àwọn ènìyàn Bẹ́ńjámínì ń gbé) ń ti ibi iṣẹ́ rẹ̀ bọ̀ láti inú oko.

Onídájọ́ 19

Onídájọ́ 19:6-21