Onídájọ́ 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

fi ìlú náà sílẹ̀ láti wá ibòmíràn láti máa gbé. Ní ojú ọ̀nà àjò rẹ̀, ó dé ilẹ̀ Míkà nínú àwọn ilẹ̀ òkè Éfúráímù.

Onídájọ́ 17

Onídájọ́ 17:1-13