Onídájọ́ 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà, Míkà sì ní ojúbọ kan. Òun sì ra èwù Éfódì kan, ó sì ṣe àwọn ère kan, ó sì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin ṣe àlùfáà rẹ̀.

Onídájọ́ 17

Onídájọ́ 17:1-13