Onídájọ́ 16:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúsónì dá a lóhùn wí pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fi okùn tútù méje tí ẹnìkan kò sá gbẹ dè mí, èmi yóò di aláìlágbára bí i gbogbo àwọn ọkùnrin yóòkù.”

Onídájọ́ 16

Onídájọ́ 16:1-10