Onídájọ́ 16:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì mú kí Sámúsónì sùn lórí itan rẹ̀, òun sì pe ọkùnrin kan láti fá àwọn ìdì irun orí rẹ̀ méjèèje, òun sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣẹ́gun rẹ̀ (dá a lóró). Agbára rẹ̀ sì fi í sílẹ̀ lọ.

Onídájọ́ 16

Onídájọ́ 16:18-27