Onídájọ́ 15:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúsónì sì wí pé,“Pẹ̀lú egungun àgbọ̀n ìsàlẹ̀ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kanMo sọ wọ́n di òkìtì kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.Pẹ̀lú egungun àgbọ̀n ìsàlẹ̀ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kanMo ti pa ẹgbẹ̀rún ọkùnrin.”

Onídájọ́ 15

Onídájọ́ 15:15-20