Onídájọ́ 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó fi ọwọ́ ha jáde, ó sì ń jẹ ẹ́ bí ó ti ń lọ. Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ àwọn òbí rẹ̀, ó fún wọn ní díẹ̀, àwọn náà sì jẹ, ṣùgbọ́n kò sọ fún wọn pé ara òkú kìnnìún ni òun ti rí oyin náà.

Onídájọ́ 14

Onídájọ́ 14:3-11