Onídájọ́ 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi ìyàwó Sámúsónì fún ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ rẹ̀ nígbà ìgbéyàwó rẹ̀.

Onídájọ́ 14

Onídájọ́ 14:17-20