Onídájọ́ 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún gbogbo ọjọ́ méje tí wọ́n fi ṣe àsè náà ni ó fi sunkún, nítorí náà ní ọjọ́ keje ó sọ ìtúmọ̀ rẹ̀ fún un nítorí pé ó yọ ọ́ lẹ́nu ní ojoojúmọ́. Òun náà sì sọ ìtúmọ̀ àlọ́ náà fún àwọn ènìyàn rẹ̀

Onídájọ́ 14

Onídájọ́ 14:15-20