Onídájọ́ 14:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
1. Nígbà kan Sámúsónì gòkè lọ sí Tímínà níbẹ̀ ni ó ti rí ọmọbìnrin Fílístínì kan.
2. Nígbà tí ó darí (padà sílé) dé, ó sọ fún àwọn òbí rẹ̀ (baba àti ìyá rẹ̀) pé, “Mo rí obìnrin Fílístínì kan ní Tímínà: báyìí ẹ fẹ́ ẹ fún mi bí aya mi”