Onídájọ́ 13:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obínrìn náà sì bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Ṣáḿsónì. Ọmọ náà dàgbà Olúwa sì bùkún un.

Onídájọ́ 13

Onídájọ́ 13:17-25