Onídájọ́ 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánóà yára dìde, ó sì tẹ̀lé aya rẹ̀, nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ ọkùnrin náà ó ní, “Ǹjẹ́ ìwọ ni o bá obìnrin yìí sọ̀rọ̀?”Ọkùnrin náà dáhùn pé “Èmi ni.”

Onídájọ́ 13

Onídájọ́ 13:6-15