Onídájọ́ 11:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́fítà dá lóhùn pé, “Ìwọ lè lọ.” Ó sì gbà á láàyè láti lọ fún oṣù méjì. Òun àti àwọn ọmọbìnrin yóòkù lọ sí orí àwọn òkè, wọ́n ṣunkún nítorí pé kì yóò lè ṣe ìgbéyàwó.

Onídájọ́ 11

Onídájọ́ 11:28-40