Onídájọ́ 11:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ náà sì dáhùn pé, “Baba mi bí ìwọ bá ti jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Olúwa, ṣe sí mi gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ, ní báyìí tí Olúwa ti gba ẹ̀ṣan fún ọ lára àwọn ọ̀ta rẹ, àwọn ará Ámónì.

Onídájọ́ 11

Onídájọ́ 11:35-39