Onídájọ́ 11:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́fítà sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Olúwa pé, “Bí ìwọ bá fi àwọn ará Ámónì lé mi lọ́wọ́,

Onídájọ́ 11

Onídájọ́ 11:26-37