Ọbadáyà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, Ìwọ Témánì,gbogbo àwọn tó wà ní orí òkè Ísọ̀ní a ó gé kúrò nínú ìpànìyàn náà.

Ọbadáyà 1

Ọbadáyà 1:3-10