Ọbadáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbéraga àyà rẹ ti tàn ọ́ jẹ,ìwọ tí ń gbé inú pálapàla àpáta,tí o sì kọ́ ibùgbé rẹ sí ibi gíga,ìwọ wí nínú ọkàn rẹ pé,‘Ta ni yóò mú mi sọ̀kalẹ̀?’

Ọbadáyà 1

Ọbadáyà 1:1-9