Nọ́ḿbà 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ dúró kí n ba lè mọ ohun tí Olúwa yóò pa láṣẹ nípa yín.”

Nọ́ḿbà 9

Nọ́ḿbà 9:4-9