Nọ́ḿbà 8:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n le máa ran àwọn arákùnrin wọn lọ́wọ́ nínú Àgọ́ Ìpàdé ṣùgbọ́n àwọn fúnra wọn kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan. Báyìí ni kí o ṣe pín iṣẹ́ fún àwọn ọmọ Léfì.”

Nọ́ḿbà 8

Nọ́ḿbà 8:24-26