Nọ́ḿbà 8:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tó jẹ mọ́ àwọn ọmọ Léfì: Láti ọmọ ọdún kẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ni kí ó máa kópa nínú iṣẹ́ àgọ́ ìpàdé.

Nọ́ḿbà 8

Nọ́ḿbà 8:22-25