Nọ́ḿbà 7:80-82 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

80. Àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì méwàá tí ó kún fún tùràrí;

81. Akọ ọ̀dọ́ màlúù kan àgbò kan, àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun;

82. Akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;

Nọ́ḿbà 7